Complete lyrics and stream the original song of Ogunmola Babajide – Orisun Ogbon Lyrics

In case you have not listened to the song “Orisun Ogbon” stream below and download also mp3 song.

Ogunmola Babajide – Orisun Ogbon Lyrics

Chrs; Orisun ogbon, Orisun Oye,
Orisun ogbon, Olorun Orisun Oye,
Oro Nigeria yi o do wo re,
Orisun ogbon o Jowo bawa tun to o.

Ogbon wa ti jawa kule, koma ye wa mo oluwa,
Asise sise ise wa o mama yo,
laala yi poju, osise wa dabi ole,
Orisun ogbon oo jowo bawa tun to o

Olorun ko fara ni wa, awa lan nira wa lara,
Abo lowo oko eru, a tun kora wa leru oo
Ijinigbe, igbe sumomi yi ti poju Oluwa,
Orisun ogbon oo Jowo bawa dasi o e

Ologun ti see, won o mariise rara o,
Alagbada tun see nise lotun le koko si o
Afi kolorun, kobawa da soro yi o,
Orisun ogbon o, Jowo bawa tun to ooo

Ojojumo labiyamo n sunkun o
Ogun niwa, ogun leyin odowo re,
Awon oloriwa tise titi, koma ma yo,
Ajakale arun tao gboruko re ri lo gbode kan,
Afi korisun ogbon ko bawa yan ju oro yio
Onisegun nla o, Jowo wa wolee wa san.

Oni to ba ku ogbon feni keni kobeereo
Baba a un beere ogbon fawon aladariwa
Naijiria loruko Jesu gba ite si wa ju
Olorun mimo o jowo wa wo lee wa san.

Related Music Lyrics

READ ALSO:  SABA Lyrics: Fearmonger Lyrics